Àwọn Àyọkà Wikipedia ń fẹ́ Àwòránaa
Wikipedia Pages Wanting Photos (WPWP) jẹ́ ìdíje ti ọlọ́dọọdun tí àwọn olọ́òtú Wikipedia káàkiri àgbáyé maá ń fí àwòrán tún ojú ewé àyọkà ṣe ní gbogbo èdè Wikipedia pátá. À ń ṣe èyí láti ṣe ìmúlò àwọn àwòrán tí à gbà látàri oríṣiríṣi ètò àtí àwọn ìdíjé tí ó n gba àwọn wọlé fún lílò ní àyọkà Wikipedia. Àwòrán wíwò maá fani mọ́ra jú kíkà lọ, tí ó sì maá n jẹ́ kí òye àyọka yéni yékéyéké.
Ẹgbẹgbẹ̀rú àwọn àwòran ní wọ́n ti gbé sí Wikimedia Commons látàri oríṣiríṣi ètò àtí àwọn ìdíjé bíi Wiki Loves Monuments, Wiki Loves Africa, Wiki Loves Earth, Wiki Loves Folklore tí ó sì jẹ́ wípé díẹ̀ nínú àwòrán wọ̀yí ní wọ́n ń ò fi tún àyọkà Wikipedia ṣe. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọnù àwòrán ni ó wà ní Wikimedia Commons lónìí ṣùgbọ́ bíńti ni wọ́n ti lò tún ojú ewé àyọkà ṣe.
Bí ẹ ṣe lè darapọ̀ mọ́ ìdíje yí
Before participating, it is important to read all rules below in their entirety. Failure to do so may result in disqualification.
- Forúkọ wọlé tàbí kí o ṣẹ̀dá orúkọ lóri Wikipedia (O ṣẹ̀dá orúkọ ní èyíkéyí àwọn èdè Wikipedia, pàápàá jùlọ èdè abínibí rẹ). O lè rí gbogbo àwọn èdè tí Wikipedia wà ni ibí.
- Ṣe àwárí àyọkà tí ó fẹ́ fi àwòrán túnṣe. Wọlé síbí kí o ṣàwárí àkọ́lé àyọkà. O tún lè lo ojú ewé àrìnàko fi ṣàwárí àyọkà.
- Láti ṣàyàn àwòrán tí ó bá àyọkà mu wọlé síbí, kí o sì ṣàwárí rẹ̀ níbí kí o sì ri dájú wípé orúkọ àwòrán tí o fẹ́ lò ṣe rẹ́gí. O sì lè ṣe àwárí nínu ìsọ̀rí. Fún àpẹẹrẹ Wiki Loves Africa ìsọ̀rí.
- Lórí àyọkà, tẹ ṣàtúnṣe kí o sì fi àwòran tí a sàlàyé rẹ̀ lókè yìí si, pẹ̀lú àpèjúwe ráńpẹ́. Ṣe àyẹ̀wo rẹ kí o tó ṣatẹ̀jáde rẹ̀ ní "Àyẹ̀wò" kí o ṣàtúnṣe tí ó bá yẹ. Kí o tẹ "Ṣàtẹ̀jáde ojú ewé".
- O tún lè kópa látàri kíkọ àyọkà tuntun pẹ̀lu àwọ̀n tí ó dára.
- Please be mindful of the image syntax! If you are going to add images to the infoboxes in articles, the syntax is a lot easier — just the filename, so rather than
[[File:Obamas at church on Inauguration Day 2013.jpg|thumb|The Obamas worship at [[African Methodist Episcopal Church]] in Washington, D.C., January 2013]]
simplyObamas at church on Inauguration Day 2013.jpg
.
Here, the caption is The Obamas worship at African Methodist Episcopal Church.
If you are going to add images to the infoboxes in articles, add them to the correct position as shown below.
| image = Obamas at church on Inauguration Day 2013.jpg
| caption = The Obamas worship at African Methodist Episcopal Church
Àwọn alàkalẹ̀ àti òfin ìdíje WPWP rèé:
Ẹ gbọ́dò lo àwọn àwòrán orí Wikimedia Commons nípa ṣíṣàfikún rẹ̀ sí àwọn àyọkà tí kò ní àwòrán láti ọjọ́ Kíní oṣù Kéje sí ọjọ́ Kẹtàlélọ́gbọ̀n oṣù Kẹjọ ọdún 2020. (1st June to 31st August 2020) |
Kò sí òdiwọ̀n fún iye àwòrán tí o lè ṣe àfikún rẹ̀ lásìkò ìdíje yí. Ẹ̀wẹ̀, àwọn ẹbùn ni ó yàtọ̀ síra wọn. Ẹ lè wo àwọn ìtọ́ka ìsàlẹ̀ yí |
Àwọn àwòrán náà gbọ́dò jẹ́ èyí tí ó ní abẹ́ 'àṣẹ ìfínífíndọ̀ ọlọ́fẹ̀ẹ́' tàbí kí ó wà ní ibi tí a ti lè lòó lọ́fẹ̀ẹ́ ní àwùjọ wa. Àwọn àṣẹ ìfínúfíndọ̀ ni: CC-BY-SA 4.0, CC-BY-40,CC0 1.0 |
Èyíkéyí olùkópa ti gbọ́dọ̀ ní àkọpamọ́ oníṣẹ́ ní orí ìkànì èyíkéyí Wikipẹ́díà. Sign in tàbí Create a new account. O sì lè fi orúkọ oníṣẹ́ rẹ sílẹ̀ ní orí Wikipẹ́díà ti èdè abínibí rẹ. Wo àtòjọ gbogbo àwọn ìkànì Wikipẹ́díà níbí |
Àwòrán tí ó bá ṣàfikún rẹ̀ gbọ́dọ̀ mọ́lẹ̀ kete kete, kí ó sì sọ ní ṣókí nípa àwòrán náà.
|
Gbogbo olùkópa nínú ìdíje yí gbọ́dọ̀ fi àmì ìdámọ̀ "#WPWP" sí abẹ́ ìkádí àwọn àyọkà tí ó bá ṣàfikún rẹ̀. Bí àpẹẹrẹ : "" èyíni àwòrán Tayé #WPWP"" |
Báwo ni ó ṣe wù yín láti darapọ̀ mọ́ ìdíje #WPWP?
A ti ṣètò oríṣirí ìlànà kalẹ̀ tí yóò bá ìlànà èyíkéyí tó lè bá ọnàkọnà tí kò báà wù ọ́ láti gbà kópa nínú ìdíje WPWP. Tẹ bọ́tìnì ìsàlẹ̀ yí láti ìṣàwárí àwọn ìlànà tí a ti ṣàgbékalẹ̀ náà fún ọ.
Gbèdéke àskò ìpolongo
Ìdíje yìí jẹ́ ọlọ́dọọdún, tí ó máa bẹ̀rẹ̀ ní oṣù keje ọdún 2020. À ó ṣe ìkéde ọjọ́ àti àkọ́lé ti ọdún yìí.
- Ọjọ́ tí ó bẹ̀rẹ̀: 1st July, 2020 00:01 (UTC)
- Ọjọ́ tí ó parí: 31st August, 2020 23:59 (UTC)
- Ọjọ́ tí a ó kéde èsì gbogbo gbò: 30th September, 2020
Ìsọ̀rí àwọn ẹ̀bùn fún àwọn tó bá jáwé olúborí
Àwọn ìsọ̀rí ẹ̀bùn fún àwọn olùdíje tí ó leregedé jùlọ nípa ṣíṣàfikún àwòrán
- Ẹ̀bùn Kíní US$500
- Ẹ̀bùn Kejì US$400
- Ẹ̀bùn Kẹta US$300
Ẹ̀bùn àwọn tí wọ́n bá ṣàfikún fọ́rán ohùn (audio) tó dára jùlọ sí àyọkà Wikipẹ́díà.
- US$200
Ẹ̀bùn àwọn tí wọ́n bá ṣàfikún fọ́rán dídíò (vidio) tó dára jùlọ sí àyọkà Wikipẹ́díà.
- US$200
Ẹ̀bùn àwọn tí wọ́n bá ṣàfikún àwòrán tó dára jùlọ sí àyọkà Wikipẹ́díà.
- US$200
Àwọn ìsọ̀rí ẹ̀bùn fún àwọn olùdíje tí wọ́n lo àwọn àwòrán Wiki Loves Africa lórí
Igbo, Swahili, Yorùbá, Luganda, Hausa, Shona, Amharic, Lingala àti Afrikaans Wikipedias. More info.
- USWiki Loves Africa 2020/Illustrate Wikipedia articles#Participation to WPWP Campaign00
Wiki Loves Folklores Prizes
The Wiki Loves Folklore is offering prizes for users with the most Wiki Loves Folklore image usage on any language Wikipedia. For more information about the Wiki Loves Folklore category of prizes, see here and click here to visit the English Wikipedia page.