Jump to content

Ìṣèlú àti Ìṣàkóso Ìyípadà/Àtúlẹ̀/Àtẹ̀sílẹ̀

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Termbase and the translation is 100% complete.
Outdated translations are marked like this.

A

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
abuse filter aṣẹ́ ìlòkulò
accountability ètò-ìṣirò
admin alákoso
administrator alákoso
administrators àwọn alákoso
administrators on meta àwọn alákoso lórí meta
adminship ìṣàkóso
advanced rights àwọn ohun-èlò gíga
advisor onímọ̀ràn
Advisory Board Ìgbìmọ̀ àwọn onímọ̀ràn
AffCom AffCom
affiliate ẹ̀ka
affiliates àwọn ẹ̀ka
Affiliations Committee Ìgbìmọ̀ fún àwọn ẹ̀ka
Africa Áfíríkà
arbitration committee Ìgbẹ́jọ́ lọ s'ókè
appeal ìgbẹ́jọ́
Assistant election official Àgbàṣẹ́ tó ń bójú tó àwọn ìdìbò
autoconfirmed users àwọn oníṣe tó jẹ́ alájẹ̀múṣẹ
autopatrolled users àwọn tó ń ṣe àbójútó àkànṣe

B

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
backlog iṣẹ́ fún ṣíṣe
best practices àwọn ìṣe tó dára jùlọ
board ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́
board election ìdìbò fún ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́
board elections ìdìbò fún ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́
Board Governance Committee Ẹgbẹ́ ìdarí ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́
board handbook ìwé ìlànà ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́
Board of Trustees Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́
BoT Roboti
bot roboti
bylaws àwọn òfin

C

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
Call for feedback Ìpè fún èsì
candidate olùdíje
candidates àwọn olùdíje
category ẹ̀ka
CEE CEE
Central and Eastern Europe Àárín Gbùngbùn àti Ìlà Oòrùn Yúróòpù
Central and Eastern Europe (CEE) and Central Asia Àárín Gbùngbùn Àríwá àti Ìlà Oòrùn Yúróòpù (CEE) àti Àárín Gbúngbà Àríwá Éṣíà
CentralNotice Ìròyìn Àkànṣe
chair alágàa
Chairman Emeritus Alaga Emeritus
challenge ìpèníjà
change àtúnṣe
changes awọn àtúnṣe
chapter ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
chapters àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
chapters agreement adéhùn àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
Chapters committee Ìgbìmọ̀ àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
chapters handbook iwé-ìlànà àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
Chapters meeting Ìpàdé àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
Charter Ìwé-àdéhùn
Charter content Ọ̀rọ̀ ìwé-àdéhùn
Charter drafting Kíkọ ìwé-àdéhùn
CheckUser CheckUser
CheckUser policy ṢayẹwoIṣakoso olumulo
Chief Operational officer Olórí Òṣìṣẹ́ fún Àwọn Iṣẹ́-ṣíṣe
Chief Technical Officer Olórí Òṣìṣẹ́ fún Ìmọ̀-ẹ̀rọ
ComCom ComCom
commission ìgbìmọ̀
committee ìgbìmọ̀
Commons Àwọn aráàlú
Communications committee Ìgbìmọ̀ fún ìbáraẹnisọ̀rọ̀
communities àwọn ará àjọṣepọ̀
communities and organizations àwọn ará àti àjọ àjọṣepọ̀
community ará àjọṣepọ̀
Community Affairs Committee Ìgbìmọ̀ fún Àlámọrí àwọn Ará Àjọṣepọ̀
Community Development Ìdàgbàsókè àwọn Ará Àjọṣepọ̀
Community Development team Ẹgbẹ́ Ìdàgbàsókè àwọn Ará Àjọṣepọ̀
community meeting Ìpàdé àwọn ará àjọṣepọ̀
Community Resilience and Sustainability (CR&S) Àgbéró àti Ìpẹ́láyé àwọn Ará Ajọṣepọ̀
conflict of interest ìtakò ànfààní
consensus ìpohùnpọ̀
consultation ìkànsí
consultation with ikànsí pẹ̀lu
consultation with communities ìkànsí pẹ̀lu àwọn ará àjọṣepọ̀
consultations àwọn ìkànsí
content ọ̀rọ̀
contractor agbaṣẹ́ṣe
contributor(s) (àwọn) olùdásí
conversation ìjíròrò
conversations àwọn ìjíròrò
coordinating nṣ'ètò
coordination ìṣètò
Council Ìgbìmọ̀

D

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
desktop tabili kọmputa
development ìdàgbàsókè
development of ti ìdàgbàsókè
Diff blog Búlọ́ọ̀gì diff
Direction Ìtọ́sọ́nà
disambiguation àtúpalẹ̀-ọ̀rọ̀
discussion ìjíròrò
discussion page ojú-ewé ìjíròrò
Discussion Tools Ohun-èlò fún Ìjíròrò
discussions àwọn ìjíròrò
diverse onírúurú
diversity onírúurú
draft ọ̀rọ̀-àkọ́kọ́
drafting kíkọ
Drafting committee Ìgbìmọ̀ fún kíkọ
drafts àwọn ọ̀rọ̀-àkọ́kọ́

E

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
East, Southeast Asia, and Pacific Ìlà Oòrùn, Gúúsù Ìlà Oorun Éṣíà àti Òkun Pàsífíìkì
edit conflict rògbòdìyàn àtúnṣe
edit summary àkótán àtúnṣe
edit war ìjà lórí àtúnṣe
Edit-a-thon Ṣàtúnṣe-à-à-ìwé
Editathon Awọn atunkọ
editing nṣ'àtúnṣe
editor olóòtú ṣiṣatunkọ
editors àwọn olóòtú ṣiṣatunkọ
election ìdìbò
Election compass Atọ́ka ìdìbò
Election officers Àwọn òṣìṣẹ́ fún ètò ìdìbò
election volunteer olùfarajìn fún ètò ìdìbò
elections àwọn ìdìbò
Elections Committee Ìgbìmọ̀ elétò Ìdìbò
Embassies Awọn ile-iṣẹ ijọba ajeji
Embassy Ile-iṣẹ ijọba ajeji
emerging communities àwọn ará àjọṣepọ̀ tó ṣẹ̀ nyọjú
emerging community ará àjọṣepọ̀ tó ṣẹ̀ nyọjú
employee òṣìṣẹ́
employees àwọn òṣìṣẹ́
enforcement ìgbófìnró
Enforcement Guideline Ìlànà ìgbófìnró
Enforcement Guidelines Àwọn ìlànà ìgbófìnró
ESEAP ESEAP
Europe Yúróòpù
evaluation ìgbéléwọ̀n
event ìpèjọ
events àwọn ìpèjọ
Events committee Ìgbìmọ̀ fún àwọn ìpèjọ
Executive Director Olùdarí Àgbà
extension itẹsiwaju
external links àwọn ìjápọ̀ àgbáyé

F, G

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
FDC FDC
feature ẹya-ara
financial committee igbìmọ̀ fún ètò ìsúná
financial reports àwọn ìjábò ètò ìsúná
Foundation Ìpínlẹ̀
Foundation-l Àtìlé-1
free knowledge imọ̀ ọ̀fẹ́
fund owó
Fundraising committee Ìgbìmọ̀ ìkówójọ
funds àwọn owó
Funds Dissemination Committee Ìgbìmọ̀ ètò Ìnáwó
General Counsel Amòfin àgbà
Gerrit Gerrit
GFDL GFDL
GLAM GLAM
GLAMs Àwọn GLAM
GLAMwiki conferences Àwọn àpèjọ-nlá fún GLAMwiki
global conversation ìjíròrò káríayé
global conversations àwọn ìjíròrò káríayé
Global council Ìgbìmọ̀ káríayé
global permissions àwọn ìgbàláàyè káríayé
global policies àwọn òfin tó káríayé
global policy òfin tó káríayé
Global Sysop Syop tó káríayé
Global Sysops Àwọn Syop tó káríayé
governance ètò ìjọba
Governance review Àtúnyẹ̀wò ètò ìjọba
grant fifunni
Grant Advisory Committee (GAC) Ìgbìmọ̀ Ìdámọ̀ràn fún fifunni (GAC)
grantee olùgb'owó
grants grant
guideline ìlànà

H, I , K

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
hackathon ìsọfúnni
healthy community àjọṣepọ̀ tí ìlera rẹ̀ péye
helpdesk tábìlì-ìrànlọ́wọ́
home wiki wiki orísun
hub ibùdó
hubs àwọn ibùdó
implement ìmúṣe
implementation ètò-ìmúṣe
inclusive ní onírúurú
initiative (Movement Strategy Initiative) initiative
insurance committee ìgbìmọ̀ ìṣèdúró
interface ojú-ìwò
interface administrator alákòso ojú-ìwò
interfaces àwọn alákòso ojú-ìwò
Interim Global Council Adelé Ìgbìmọ̀ Káríayé
interwiki interwiki
IRC IRC
knowledge ìmọ̀

L

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
LangCom LangCom
Language Committee Ìgbìmọ̀ Èdè
LATAM LATAM
Latin America Latin America
Latin America (LATAM) and The Caribbean Latin America (LATAM) àti Caribbean
leader Olórí
leadership Ìdarí
Leadership development Ìdàgbàsókè ìdarí
Leadership development working group Ẹgbẹ́ iṣẹ́ fún ìdàgbàsókè ìdarí
legal t'olófìn
legal officer Òṣìṣẹ́ t'olófìn
libraries àwọn ilé-ìkàwé
library ilé-ìkàwé
list of chapters àtòjọ àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia
list of projects àtòjọ àwọn iṣẹ́-àkànṣe
lists of projects àtòjọ àwọn iṣẹ́-àkànṣe
logo àwòrán-ìdánimọ̀
logos àwọn àwòrán-ìdánimọ̀

M, N

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
mailing list mailing list
mailing lists àwọn mailing list
main page ojúewé àkọ́kọ́
mainspace ààyè-gbogboògbò
maintaining nṣètọ́jú
matching fund owó ìbámu
MediaWiki MediaWiki
MENA MENA
Meta policies Àwọn òfin Meta
Middle East and Africa Middle East àti Áfíríkà
mission statement ọ̀rọ̀ àfojúsùn
movement àjọṣepọ̀
Movement Charter Ìwé-àdéhùn Àjọṣepọ̀
Movement Strategy Strategy Àjọṣepọ̀
movement-wide kárí-Àjọṣepọ̀
multilingual project iṣẹ́-àkànṣe onírúurú-èdè
multilingual projects àwọn iṣẹ́-àkànṣe onírúurú-èdè
namespace ààyè-ọ̀rọ̀
namespaces àwọn ààyè-ọ̀rọ̀
need for leadership ìní fún ìdarí
needs àwọn ìní
Neutral point of view (NPOV) Ìrísí Àìlójúṣájú (NPOV)
newcomer ẹni titun
newcomers àwọn ẹni titun

O, P

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
office action ìgbésẹ̀ ilé-iṣẹ́
office actions àwọn ìgbésẹ̀ ilé-iṣẹ́
officers àwọn òṣìṣẹ́
office hour(s) wákàtí (wákàtí) àwọn òṣìṣẹ́
online platform pẹpẹ ayélujára
online tool ohun-èlò ayélujára
organization àjọ
organizations àwọn àjọ
outreach ìpolongo
oversight àbójútó
page ojúewé
paid editing ìṣàtúnṣe t'olówó
participant olùkópa
participants Àwọn olùkópa
permissions àwọn ìgbàláàyè
platform pẹpẹ
platforms àwọn pẹpẹ
point of view (pov) ìrísí (pov)
policies àwọn òfin
policy òfin
presentation àgbéjáde
presentations àwọn àgbéjáde
priorities ìwò àwọn ohun-pàtàkì
prioritized múní pàtàkì-jùlọ
priority ohun pàtàkì-jùlọ
priority initiative àfojúsùn pàtàkì-jùlọ
priority initiatives àwọn àfojúsùn pàtàkì-jùlọ
privilege àǹfààní
process ètò
processes àwọn ètò
project iṣẹ́-àkànṣe
projects àwọn iṣẹ́-àkànṣe
proposal ìbẹ̀wẹ̀
proposals àwọn ìbẹ̀wẹ̀

R

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
random page ojú-ewé èyíkèyí
ratification ìfọwọ́sí
ratification process ètò ìfọwọ́sí
recent changes ojúṣe
recommendation padàsẹ́hìn
recommendations owó-ìwọlé
red link àwọn owó-ìwọlé
redirect Tábílì-ìjíròrò
Regional hub SAARC
Regional hubs àpótí-àdánwò
rename sàkání
request yíyàn
request for permissions ìwọlé ọ̀kan f'oníṣẹ́
requests ibeere
requests for permissions àwọn ìbéèrè fún àṣẹ
requests for username changes àwọn ìbéèrè nípa yípa orúkọ oníṣe
research Iwadi
research phase Ipele iwadi
research report ijabọ ìwádì
research result àbájáde ìwádì
resource ohun ìní
resources àwọn ohun ìní
responsibilities àwọn ojúṣe
responsibility ojúṣe
retreat ìtìlẹyìn
revenue owó tó ń wọlé
revenues àwọn owó tó ń wọlé
right ọ̀nà tó tọ́
Roundtable Tabili ìyíká

S

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
SAARC Àwọn aráàlú
sandbox àpáta àpáta
scope àyè tí wọ́n lè lò
section apá
selection ìdìbò
single user login ìkànnì ìkànnì oníṣe kan ṣoṣo
sister projects àwọn iṣẹ́-àkànṣe mìíràn
skills development ìdàgbàsókè ìmọ̀ṣe
Small Wiki Monitoring Team Ẹgbẹ́ Alámòjútó Àwọn Wiki Kékeré
South Asian Association for Regional Cooperation South Asian Association for Regional Cooperation
spam ìsọfúnni tí kò tọ́
spam block list Àkọsílẹ ìsọfúnni tí kò tọ́ ti di
special page ojú-ewé pàtàkì
special pages àwọn ojú-ewé pàtàkì
speedy deletion ìparẹ́ ní kánkán
speedy deletions àwọn ìparẹ́ ní kánkán
staff àwọn òṣìṣẹ́
stakeholder alátìlẹ́yìn
stakeholders àwọn alátìlẹ́yìn
steward iriju
steward elections ìdìbò àwọn iriju
steward requests àwọn ohun tí iriju ń béèrè
stewards àwọn iriju
strategy strategy
strategy recommendation ìmọ̀ràn strategy
strategy recommendations àwọn ìmọ̀ràn strategy
SUL SUL
summaries àwọn àkọ́tán
summary àkọ́tán
support àtìlẹ́yìn
suppression ìfòòró
sustainability ìpẹ́láyé
sysop syop
sysops àwọn syop

T

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
talk page ojú-ewé ọ̀rọ̀
talk pages àwọn ojú-ewé ọ̀rọ̀
task force agbófìnró
Telegram Group Ẹgbẹ́ Telegram
Telegram Groups Àwọn ẹgbẹ́ Telegram
template àdàkọ
templates àwọn àdàkọ
test wiki wiki ìdánwò
test wikis àwọn wiki ìdánwò
thematic hub ibùdó àkórí
thematic hubs àwọn ibùdó àkórí
thematic organization àjọ àkórí
thematic organizations àwọn àjọ àkórí
trademarks committee ìgbìmọ̀ àmì-òwò
transclusion àtúpalẹ̀
translation of the week ìtúmọ̀ ti ọ̀sẹ̀
translation request ìbéèrè fún ìtúmọ̀
translation requests àwọn ìbéèrè fún ìtúmọ̀
treasurer akápò
Trust & Safety Trust & Safety
trustee onígbọ̀wọ́
trustees àwọn onígbọ̀wọ́

U, V

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
UCoC Enforcement guidelines Àwọn ìlànà ìgbófìnró UCoC
United States and Canada United States àti Canada
Universal Code of Conduct Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí
update ìmúdójúìwọ̀n
user oníṣẹ́
user group ẹgbẹ́ oníṣẹ́
user groups àwọn ẹgbẹ́ oníṣẹ́
user page ojú-ewé oníṣẹ́
vandal onídàrú
vandalism ìdàrú
vandals àwọn onídàrú
verifiability ìwádìí
vice-chair igbákejì alága
village pump abẹ́ igi
VisualEditor VisualEditor
Volunteer Response Team Ẹgbẹ́ Olùfarajìn fún Ìdáhùn

W

Gẹ̀ẹ́sì Ìtúmọ̀
Wikibooks Wikibooks
Wikicouncil Wikicouncil
Wikimania Wikimania
Wikimedia Wikimedia
Wikimedian Wikimedian
Wikimedia Cloud Services (WMCS) Wikimedia Cloud Services (WMCS)
Wikimedia Commons Wikimedia Commons
Wikimedia community Àjọṣepọ̀ Wikimedia
Wikimedia Foundation Wikimedia Foundation
Wikimedia Foundation official policies Àwọn òfin iṣẹ́ Wikimedia Foundation
Wikimedia Foundation official policy Òfin iṣẹ́ Wikimedia Foundation
Wikimedia project Iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia
Wikimedia projects Àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia
Wikimedia Summit Wikimedia Summit
Wikinews Wikinews
Wikipedia Wikipedia
Wikiquote Wikiquote
Wikisource Wikisource
Wikispecies Wikispecies
wikitext wikitext
wikitext editor wikitext editor
Wikiversity Wikiversity
Wikivoyage Wikivoyage
Wiktionary Wiktionary
working group ẹgbẹ́ iṣẹ́