Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation/Àkópọ̀
Appearance
Outdated translations are marked like this.
Wikimedia Foundation
Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́
The Wikimedia Foundation has a Board of Trustees to oversee the Wikimedia Foundation's strategy. They approve the priorities of the Foundation and the resources needed to deliver them. Board members are not paid for their work and are volunteers – they bring together different viewpoints and perspectives to their decisions. You can have your say on who is on the board by voting. |
Yíyàn fún àwọn àga lát'ọ̀dọ̀ ìgbìmọ̀ má nwáyé nípa ètò ìwárii kárí-ayé. Wọn yí ò darapọ̀ mọ́ ìgbìmọ̀ nígbàtí ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́ àti ẹni-ayàn náà bá ti gbà wípé iṣẹ́ náà yẹ fún wọn. |
Àwọn onígbọ̀wọ́ yí ò jọ̀wọ́ wákàtí 150 fún iṣẹ́ wọn lọ́dọọdún. Wọn yí ò ṣiṣẹ́ nínú ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ orí ìgbìmọ̀ náà. Lára àwọn ẹgbẹ́ yìí ni: Board Governance, Audit, Human Resources, Product, Special Projects, àti Community Affairs. |
Mọ̀ si nípa Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ àti bíí o ṣe lè kópa nínú ìdìbò ìgbìmọ̀ yìí lórí: https://w.wiki/yY9. |