Jump to content

Global AbuseFilter/2014 announcement/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Global AbuseFilter/2014 announcement and the translation is 60% complete.
Outdated translations are marked like this.

Ẹ kúu lẹ̀,

AbuseFilter je botinni MediaWiki ti a maa n lo lati dena ilokulo ikanni yii, awon alase lori ikanni yii maa n gbiyanju lati wo awon nnkan ti o n sele lori ikanni naa, won si maa n fa awon oro kobakungbe tabi awon ohun ti o ba je mo ilokolo ikanni yii. AbuseFilter le pinnu lati je ki awon isofunni kan see foju ri tabi ki won ma see foju ri.

AbuseFilter le pa isofunni meji ti o je ikan na latokedele papo, o le gbe isofunni kan lati isori ikanni kan lo si omiran, o si le gba awon isofunni wole ati awon nnkan peepeepe miiran. O tiel e le pinnu ohun ti o bogbon mu ju lati se ti o ba rii pe isofunni kan je ikan naa latokedele pelu omiran ti o ti wa tele, O le pinnu lati gba-a wole, fi ami ikilo sii lori tabi ki o tie dena eni ti o gbe isofunni naa wole. Ni afikun O maa n se akosile awon isofuuni ti o ba mu ifura lowo

A bere sii lo AbuseFilter ni odun 2009. Odun meta leyin naa a se Abusefilter ti o maa ba gbogbo ikaani Wiki sise papo lowokan (iyen GlobalAbuseFilter). Enu la fi se eto yii, bi o tile je wipe opo julo awon ti o wa ninu igbimo fowo sii, a ko se ohun gunmo kan lori re tit di odun 2013, tii di bi a se n wi yii, a ti n lo GlobalAbuseFilter ni awon isori kekere ati nla lori awon wiki wa. Sugbon, o seese ki awon wiki kan yo GlobalAbuseFilter kuro.