China-Nigeria Wiki Collaboration/Yoruba
Appearance
Main page | Rules | Articles - Nigeria | Articles - China |
Àlàkalẹ̀ ati òfin isẹ́ yí
Ní kúlúrú: Ṣe ògbufọ̀ Àwọn àyọkà tí tí ó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún àwọn oníṣẹ́ àwùjọ China, pẹ̀lú àwọn itọ́ka sí tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ láàrín ọjọ́ Kínní oṣù Keje sí ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù K UTC.
- Àwọn àyọkà yí gbọ́dọ̀ jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè (China) ati ( Nàìjíríà).
- A gbọ́dọ̀ ṣe ògbufọ̀ àwọn àyọkà yí ní àárín August 1st - August 31st, 2021 (UTC).
- Àwọn àyọkà yí gbọ́dọ̀ peregedé lórí àwọn àṣàyàn èdè.(yàtọ̀ọ̀ sí Infobox, template etc.)
- Àwọn àyọkà tí wọ́n bá ṣe ògbufọ̀ rẹ̀ gbọ́dọ̀ ní àwọn itọ́ka sí tó lọ́ọ̀rìn, tí wọ́n sì lè ní ànfaní sí itọ́ka sí wọ̀ yí.
- Àwọn àyọkà tí wọ́n bá ṣe ògbufọ̀ rẹ̀ kò gbọ́dọ̀ jẹ́ akọsílẹ̀ èyí tí a fi google ke sílẹ̀.
- Àwọn àyọkà tí wọ́n bá kọ kò gbọdọ̀ ní ìṣòro kankan.
- Àwọn àyọkà tí a bá ṣe ògbufọ̀ rẹ̀ gbọ́dọ̀ ní ìsọfúni gidi.
- Àwọn àyọkà tí a bá ṣe ògbufọ̀ rẹ̀ ni àwọn adarí àwùjọ yóò Articles submitted by an organizer need to be checked by other organizers.
- Àwọn olùyẹ̀wò ní àwùjọ Chinese/Nigerian ni yóò lè sọ bóyá àyọkà tí aláfikún kan bá ke yóò jẹ́ itẹ́wọ́-gbà ní ojú ewé Wikipedia wọn.
- Gbogbo aláfikún tí ó bá ṣe àfikún ni yóò ní ànfaní láti gba àmì Banster nínú ìdíje yí.
Àwọn àwùjọ tí ó ń kópa
- ... (Nigerian Fountain)
- ...(Chinese Fountain)