Yíyàn aláàga àjô ìpilë ilëìsôlë Wikimedia ti ôdún 2013
The election ended 22 June 2013. No more votes will be accepted. The results were announced on 24 June 2013. |
Awon alaga iduro ti ajo yi ma se awon ise pataki ni awujo. Awon ise naa pelu ki won ma be ise ti ajo ba da le won lowo wo, ki won ma se ojuse ise naa gege bi won se yan won, ki won de tun ma fun awon alaga iduro to ba won pese ni imoran ati imoye ti won lee ma fi mo asa ati ona ti o ye lati le ba ise idibo ati yiyan awon alaga de opin.
ara/ ômô egbê
Awon alaga iduro ti won yan lati le ma be idibo naa wo lo ma yanju awon ise ti o kan yiyan awon alaga ajo wonyi fun wikimedia ti odun yi ti a wa, odun wa 2013. Awon ti won yan gege bi ara alaga iduro gbodo je eniyan ti o maa n'da awon iwe ko lori Wikimedia ti won de ti ko iwe to ju meji lo, won o de lee je Oludasile tabi ki won tun je eniyan ti o wa larin awon ti a maa yan.
Ikedelojo karun osu keji odun 2013, awon alaga idibo ti won yan ni
Oruko | Ede | Ilu ati ona ago ni ilu naa |
---|---|---|
Ferdinando Scala | it, nap, en-5, fr-5, es-2 | San Giorgio a Cremano, Italy (UTC+1) |
Jon Harald Søby | nb, en-3, sv-3, de-2, da-2, es-1, eo-1, ro-1, sw-1 | Trondheim, Norway (UTC+1) |
Katie Chan | en, yue | Lincoln, England (UTC+0) |
Ralf Roletschek | de, es-2, ru-1, cs-1, ca-1, en-0 | Eberswalde, Germany (UTC+1) |
Risker | en, fr-2 | Toronto, Canada (UTC-5) |
Phillippe Beaudette ni o duro lati ran awon osise lowo, lati gba won ni imoran ati imoye pelu Geoff Brigham lati ran won lowo lori oro ofin ati oye
Ise
Awon alaga iduro idibo yio ma to ona ti idibo yio fi seese fun gbogbo awon asa ati ise pataki fun ibo naa.(ends at for example) not tonemarked...