Ìpadé àpérò strategy gbogbo Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ tí ó wáyé ní inú ọdún 2020
Ìpàdé àpérò yí ni ó dá lé ìfohùn-ṣọ̀kan awọn oníṣẹ́ Wikimedia ni gbogbo Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀, láti lè jẹ́ kí gbogbo awọn ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ ó lè kópa tí ó lààmì-laaka àti kí ìbáṣeoọ̀ tó mọ́yán lórí ó láàrín ajọ Wikimedia àti awọn oníṣẹ́ Wikimedia jákè-jádò Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀.
Àwọn kókó ọ̀rọ̀ tí ó ṣe pàtàkì
- Déètì: ọjọ́ Kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kẹwàá ọdún 20209
- Ibi yí ó ti wáyé: "Zoom"
- Àkálẹ̀ fọ́rán fídíò [$ur|Zoom]
- Notes: [$ur| Notes Link]
- Iye àwọn olùkópa: 92
Àfojúsùn
Àpérò Àmúse-múlò gbogbo gbò ilẹ̀ Adúláwọ̀ ni wọ́n ṣe láti lè mú awọn àfojúsùn wọ́nyí ṣẹ:
- Láti lè jẹ́ kí àwùjọ àwọn oníṣẹ́ ó lè kópa
- Ṣíṣe akọsílẹ̀ awọn èrò ati bí a ṣe lè mú awọn èrò àmúṣe-múlò(strategy).
- Ṣiṣẹ́ ìpolongo àwọn ìgbésẹ̀ àti ìròyìn nípa ọ̀nà àmúṣe-múlò (strategy) fún àwọn oníṣẹ́ àwọn Wikimedia ní Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀.
- Ṣiṣẹ́ àmójútó
Àwọn olùkópa
- Abderamane Abakar Brahim
- Abdulfatai Mustapha
- Abigail York
- Aboubacar Keita
- Adaora Obuezie
- Adebayo Fawaz Tairou
- Ahmat Mahamat Tahi
- Amanda Keton
- Antoni Mtavangu
- Aquila Ayo
- Ayokanmi Oyeyem
- Azibert Abdallah
- Bobby Shabangu
- Bukola James
- Candy Khohliwe
- Chima Asogwa
- Chinelo Okonkwo-Chukwunweike
- Chris Azorbli
- Constance Azogbonon
- Douglas Erunayo
- Dumisani Ndubane
- Ebuka Hero
- EGBUNIWE CYNTHIA
- Emmanuel Yeboah
- Enock Seth Nyamador
- Erina Mukuta
- Espérance HOUNNOU
- Euphemia Uwandu
- Faith Mwanyolo
- FAUZIYAH NIHINLOLAWA ADENEKAN
- Felix Nartey
- Friday Udeji
- Gbemisola Esho
- Geoffrey Kateregga
- Gilbert Ndihokubwayo
- Haruna Shu'aibu
- Hugues Coba
- Iddy John
- Isaac Olatunde
- James Bondze
- Jamima Antwi
- Janeen Uzzell
- Jemima Antwi
- Jesse Akrofi
- John Obell
- Jonathan Oberko
- Joris Quarshie
- Joy Agyepong
- Justice Okai-Allotey
- Kaarel Vaidla
- Kamaluddeen Isa El-Kalash
- Katherine Maher
- Kayode Yussuf
- Leonard Kisuu
- Lisa Steitz-Gruwell
- Maxwell Beganim
- Mehrdad Pourzaki
- Mikaeel Sodiq
- Mo Ajala
- Mohammed Alliyu
- Nadaine Samira Iddrisu
- Nebiyu Sultan
- Nerus KOLADE
- N'fana DIAKITE
- Ngozi Perpetua
- Nkem Osuigwe
- Noreen
- Obiageli Ezeilo
- Oboubé Blanchard DJOSSOU
- Oby Ezeilo
- Onyinye Onuoha
- Rachad Sanoussi
- Rajeeb Dutta
- Rebecca Adengbono
- Ruby D-Brown
- Ryan Merkley
- Sadik Shahadu
- Sam Oyeyele
- Sami Mlouhi
- Sandister Tei
- Selorm Ayikoe
- Selorm Danyo
- Stella Agbley
- Stephen Dakyi
- Tochi Precious
- Uzoma Ozurumba
- Valentin Nasibu
- Wilson Oluoha
- Winnie Kabintie
- Yamen Bousrih
- Yves Sefu Madika
- Zita Sage
Àwọn ohun èsì tí a ń retí lẹ́yìn àpérò náà
A ń retí kí àwọn ìgbìmò alámòójútó àwùjọ àwọn oníṣẹ́ Wikimedia ní Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ ó tún ṣe ìpàdé ẹlẹ́kùn ò jẹkùn ní àwùj wọn ṣáájú ìpadé àpérò àpapọ̀ gbogbo àwọn Oníṣẹ́ àti ajọ Wikimedia lágbàáyé ní 21 sí 22 oṣù Kọkànlá ọdún 2020. Lẹ́yìn ìpàdé àpérò gbogbo gbò yí, awọn alámòójútó àwùjọ ẹkùn kòọ̀kan tún lè gbé ìpàdé mìíràn kalẹ̀ lẹ́yìn ìpàdé gbogbo gbò yí ní àwùjọ wọn láti lè tún mú ìlọsíwájú bá ọ̀nà àmúṣe-múlò àti èrò àjọ Wikimedia lápapọ̀ lẹ́kùn wọn.