Jump to content

Universal Code of Conduct/Coordinating Committee/Charter/Voting/Translations/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Universal Code of Conduct/Coordinating Committee/Charter/Voting/Translations and the translation is 67% complete.
Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí

This page coordinates translation of the Universal Code of Conduct Coordinating Committee charter poll question.

Dìbò

Bẹ̀ẹ́ni

Bẹ̀ẹ́kọ́

Ìbéèrè

Do you support the ratification of the Universal Code of Conduct Coordinating Committee charter?

This vote is part of the ratification process for the Universal Code of Conduct Coordinating Committee charter. Submit your vote below. For more information, refer to the voter help page on Meta-Wiki.

Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé "Bẹ́ẹ̀kọ́" tàbí "Bẹ́ẹ̀ni". Dibo pẹ̀lú yálà "Bẹ́ẹ̀kọ́" tàbí "Bẹ́ẹ̀ni" a kò ní ṣe àfihàn èyí tí ẹ yàn ní ibi òǹkà àṣẹkágbá

If you have concerns about the charter, please indicate the section or sections that are of concern and what concerns you have. Comments will be public. Please do not provide personal information in your comments. Thank you.

Other material

  • title: Universal Code of Conduct Coordinating Committee Charter Ratification
  • jumptext: Ìbò náà yóò wáyé lórí ààrin gbùngbùn wiki kan. Jọ̀wọ́ tẹ bọ́tìnì náà n'ísàlẹ̀ láti fi ránṣẹ́. Jọ̀wọ́ ríi pé nígbà tí o bá dibò ìwífún kan tí ó ní àdírẹ́sì IP rẹ tí asojú ìlò yoo jẹ́ gbígbà lati gba àwọn olùyẹ̀wọ̀ láàyẹ̀ lati s'àrídájú jíjẹ́ òótọ́ ìbò náà. Ìwífún náà yoo jẹ́ píparẹ́ ní ọjọ́ 90 lẹ́yìn ti ìdìbò bá parí yóò sí ṣeé rí fún àwọn olùyẹ̀wọ̀ àti àwọn olùdámọ̀ràn òsìṣẹ̀ ìdìbò nìkan.
  • returntext: Iṣẹ́ Òfin Ìhùwàsí Àgbáyé
  • unqualifiederror: A tọrọ gáfárà, ṣùgbọ́n o kò sí lórí àtòjọ àwọn tó l'áṣẹ láti dìbò. Jọ̀wọ́ lọsí ojú-ewé ìrànlọ́wọ́ olùdìbò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ lórí àṣe ìdìbò àti àlàyé lórí bí o ṣelè fọrúkọ s'órí àtòjọ olùdìbò tí o bá ní àṣẹ láti dìbò.