Jump to content

The Wikipedia Library/Newsletter/August-September 2017/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page The Wikipedia Library/Newsletter/August-September 2017 and the translation is 56% complete.
Outdated translations are marked like this.
Yàrá ìkàwé Wikipédíà
Àwọn ìwé àti Ìdíwọ̀n
Abala mẹ́rìnlélógún , Oṣù kẹjọ–Oṣù kẹsán 2017

Fi orúkọ sílẹ̀ fún ìfitólétí tolóṣooṣù

Ní ti abala tọ̀̀tẹ̀ yí a ṣàgbéyọ Wikimania, ìtẹ̀síwájú káàkàkiri àti pé bí a ṣe maa ń ṣe, fún àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn àti àwọn ohun èlò tí ó ní ṣe pẹ̀lú yàrá ìkàwé tí wọn máa rí lò fún ìmọ̀ ìgbàlóde ti díjítà.

Ẹgbẹ́ àwọn olótú

Ẹgbẹ́ àwọn olótú Yàrá ìkàwé Wikipédíà dí àwọn ààyè tó wà láàrín àwọn olóòtú Wikipédíà àti àwọn alábójúto yàrá ìkàwé, nípa dídúró gẹ́gẹ́ bí ibi ìpàdé tí ó sì ń rànwọ́nlọ́wọ́ láti bára wọn ṣepọ̀. Láti ìgbà tí wọ́n ti dáa sílẹ̀, ni àwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ ti ń ṣiṣẹ́ takuntakun láti wá ọ̀na tí wọ́n ó gbà tí ẹgbẹ́ yí yío fi làlùyọ. Oṣù méjì tó kọjá kún fún ìpàdé àwọn olùdásílẹ̀ méjì àti ìpàdé gbogboògbò tí ó jẹ́ ìpele méjì. Wọ́́n fi Jẹ́ a pàdé lórí afẹ́fẹ́ wo Ìpàdé gbogboògbò yìí, ìgbohùnsílẹ̀ rẹ̀ àti gbogbo ohun tí wọ́n sọ wà ní ibí. Ní ìpàdé àwọn olùdásílẹ̀, wọ́n jíròrò wípé kí wọ́n yí orúkọ ẹgbẹ́ yìí padà, tí àwọn èèyàn sí fọwọ́si. Àtipé, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ fọwọ́sí èròngbà pé kí wọ́n máa ṣe ìpàdé gbogboògbò. Ní ìpàdé àwọn olùdásílẹ̀ àti gbogboògbò, wọ́n jíròrò nípà yíyan àwọn alámójútó iṣẹ́ ẹgbẹ́, wọ́n sì gba àwọn ọmọ́ ẹgbẹ́ láyè láti fi orúkọ arawọn sílè. Wọ́n sì tún sọ̀rọ̀ nípa ìpolongo Wikipédíà Nífẹ́ Yàrá Ìkàwé. Láti ran àwọn oníṣẹ́ tuntun lọ́wọ́ kí wọ́n lè rí ìrànlọ́wọ́ nírọ̀rùn, ojú ewé mẹ́tà ti ẹgbẹ́ yìí ń di túntúnṣe lọ́wọ́lọ́wọ́. Ojú ewé gbàyíyẹ̀wọ̀ ti dínkù dáadáa, ìsọfúni rébété àti àwọn ìtọ́kasí ohun ìmúlò. Óúnbọ̀lọ́nà: Ètò ìdìbò lórí orúkọ ẹgbẹ́, àwòrán ìdánimọ̀, àti ìforúkọlélẹ̀ fún alámójútó iṣẹ́ ẹgbẹ́.

Káàkàkiri àgbáyé

Àwọn ẹ̀ka wa káàkàkiri àgbáyé ń gbòòrò sí tí wọ́n sì ń ran àwọn akọ̀wé tí ó nílò ìrànlọ́wọ́ lọ́wọ́. À ń gbìyànjú àwọn ọ̀nà ọ̀tun àti àgbéyẹ̀wò àwọn èsì rẹ̀ tí ó lè ṣe àǹfàní fún àwọn àkọ̀wé wà tí wọn kò kí ń ṣe elédè gẹ̀ẹ́sì. Ohun ọ̀tun ń ṣẹlẹ̀, tí a sì ní láti fi tó wa létí látàrí ìròyìn wa tolóṣooṣù ti a maa ń gbé jáde ní èdè oríṣirísi' lóṣù tókọjá, iye èdè tí a tẹ àwọn Ìwé àti Ìdíwọ̀n gbòòrò si tí ó sí tó ọwọ́ àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n fẹ́ ṣe ìpolongo Ìwé àti Ìdíwọ̀n wa ní àwọn èdè abínibí wọn.

Ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ alámójútó

Àmì ẹ̀yẹ alámójútó jẹ́ ètò ẹ̀bùn tí ó maa ń wáyé lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún fún àwọn alámójútó Yàrá Ìkàwé Wikipédíà fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ń ṣè lágbègbè wọ́n. Ẹni tí ó gba ti ọ̀tẹ̀ yìí ni...

Oníṣẹ́:Csisc, Tunisia
Okú oríre o Oníṣẹ́:Csisc fún ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ alámójútó fún ti ọ̀tẹ̀ yìí (Oṣù keje - Oṣù kẹsán)!!! À gbóríyìn fún ní ti ọ̀tẹ yí, fún iṣẹ́ takuntakun tí ó ń ṣe láti rí wípé a rí nkan nípa orílẹ̀ èdè Tunisia kà. Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó sọ wípé "Ó maá ń ṣòro láti rí àwọn ìtọ́kasí ní ojú òpó tí a lé lò láti kọ nípa oun tí ó ní ṣe pẹ̀lú Tunisia, èyí kò jẹ́ kí a lè kọ àyọkà tó péye ní Wikipédíà"

Ìgbìyànjú láti dẹ́kun àwọn ìṣòro wọ̀nyí ní o jẹ́ kí a dá Ẹ̀ka Yàrá Ìkawé Wikipédíà ti Tunisia sílẹ̀. Ẹ̀ka yìí máa jẹ́ kí àwọn akọ̀wé Wikipédíà látàri ètò oníṣẹ́ Wikipédíà tí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Yàrá Ìkàwé tí Medinas tí Tunisia láàfàní sí àwọn ìtọ́kasí tí ó wà lójú òpó àtí èyí tí kò sí lójú òpó, ìwé ìgbà láéláé tí ó ti di tọ̀fẹ́ tí wọ́n lè lò ní Wikisource àti abala OCR tí ó sì máa wúlò fún gbogbo àwọn onịṣẹ́ Wikipédíà pátápátá láti lò ní Wikipédíà. Ẹlè kà nípa iṣẹ́ rẹ̀ síi níbí

Sáà egbẹ́ ẹyẹ lẹyẹ ń wọ́tọ̀ ní Wikimania

Sáà egbẹ́ ẹyẹ lẹyẹ ń wọ́tọ̀ tí ó wáyé ní Wikimania fún wa ní ààyè láti ṣalábápàdé àwọn olórí àgbájọ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn yàrá ìkàwé, ìdásílẹ̀ àwọn ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtẹ̀wé jáde, ṣe àpéjọ ní àwọn ilé ìmọ̀, ṣe ìpolongo dé àwọn àjọ tílé toko. Àwọn àgbéjọ nìyí:

  • New York: combining forces with chapter to attend events and talk about getting involved with Wikipedia. Collaborated with local librarian caucus around 1lib1ref. One-on-one relationship-building improves uptake
  • Queensland librarians added over 1000 citations during 1lib1ref
  • Art+Feminism is coming up on its 5-year anniversary
  • Mexico City: project on ancient books includes digitizing and sharing via Wikisource
  • Wikimedia DC: transcribed women biographical dictionary
  • Wikimedia LGBT Twitter has been resurrected for information-sharing / promotion / collaborating and invites new followers
  • ORCID Wikipedian-in-Residence + WikiCite created plugin for Zotero, including in quick statements format for Wikidata. Also doubled ORCID IDs in Wikidata and invites others to add those of their researchers
  • York University will be among the participants in a Canada-wide music editathon planned for October. Upcoming ARL project will focus on indigenous communities in Wikidata.
  • Farsi branch of The Wikipedia Library has done outreach to local universities, has been successful in obtaining resources for every editor requesting one on Farsi
  • New module on French Wikipedia ({{bibliographie}}) allows you to enter Wikidata item to create full citation
  • OCLC Wikipedia + libraries project has raised profiles of “librarians who Wikipedia”; online training program in the fall will enroll 500 public library staff in the fall (706 enrollees at July preview)
  • Bodleian Libraries backing a project for semantic web for books, suggesting the use of Wikidata as a hub
  • Wikicite modeled representation of books in Wikidata at work and manifestation level - call for review as part of revitalization of Wikipedia+Libraries listserv
  • West Virginia University has developed programming for students to do service credit via Wikipedia training
  • London training session for public librarians - interest in serving users by better understanding Wikipedia
  • Northeastern working with student Wikipedia assignments - students find this one of the most rewarding assignments of their university career
  • Laurentian built widget that pulls data on recording artists in their catalogue from Wikidata
  • Need to find way to get faculty on board to participate in Wikipedia projects
    • Machiavellian approach: find out what people care about and explain how this can be achieved via what you want to do
  • How to avoid burnout?
    • Know when to step back
    • Be explicit about Be Bold philosophy
    • Teach people who can teach others
  • Problem with librarian contributions being reverted as spam
  • Wikipedia Library User Group as venue for collaboration and seeking help

Ààmìyàn: Àwọn ìkọsílẹ̀ Wiki Loves

Ìyàsọ́tọ̀ láti inú búlọ́ọ̀gì Wikimedia nípasẹ Benoit Rochon, Wikimedia Canada

Àwọn àkọsílẹ̀ tó pọ̀ ló dá ló rí ìjìyà lát'ọwọ́ àwọn ìdákéré ìsúna àti ìgbudọ̀ se yíyan àwọn ìgbàsílẹ̀ kọ̀kan láti tọ́ jú sí ìpalára àwọn ìmíràn. Ní àwọn ọdún tó kọjá lọ, Wikimedia Canada ti fara jìn nínu iṣẹ́ yìí láti dá sìlẹ̀ Wikipedia ní èdè àwọn Aboriginal. níní eléyì lọ́kan ni Bibliothèque et Archives nationales du Québec (BAnQ) wá pe àwọn olúgbé Montreal láti sè pamọ́ àwọn àkọsílẹ̀ àwòrán nípa sísètò scan-a-thon àkọ́kọ́.

Fun iṣẹ́ yìí àti àwọn scan-a-thon ti jọ́ wájú, Wikimedia Canada àti WikiClub ti Montreal sètò fún scanner pàtàkì, tí ó fàyè gba yíya negatives ní fíìmu resolution tó ga. Lẹ́yìín ikẹkọ kékeré láti ọ̀dọ amòye ìkọsílẹ̀, àwọn olùfarajì n fi àwọn negative sínu apó fíìmu léèkọ̀ọ̀kan, nígbàtí àwọn kan sì n sọ wọ́n di dígítà. Ní àkókò náà, àwọn olùfarajì míràn sè dájú pé kò sí eruku, pá àwọn àwòrán pé, àti ìdájú àwọn ètò tókù. Àwọn ẹgbẹ́ àwọn olùfarajì, ní abala méjèèjì ìyàrá àwòrán, gba àwọn àwòrán yìí sínu igi USB, wọ́n sìi fi wọ́n sóri Wikimedia Commons àti nígbààmíì se àpèjúwèé àwọn àwòrán náà, nítorí gbogbo wọ́n kọ́ lóní àpèjúwèé ìjìnlẹ̀. Àwọn olùkópa tókù rọ́ àwọn àpèjúwèé yìí sí àwọn èdè míràn, àti gbígbé wọn lọ sóríi ojú-ewé Wikipedia, láti sàtúnse ojú-ewé náà.

Thus at the end of the day, more than 500 images and documents, dating from as far back as the 1700s, were digitized and uploaded to Wikimedia Commons. The archives will directly benefit from this as well—through the free license on Commons, BAnQ can take and use those previously undigitized photos and descriptions in their own catalog. Once the funds were uploaded in Commons, volunteers from around the world digitally restored some of the photos by removing wrinkles, dust, and tears.

Àdánwò yìí jẹ́ àseyọrí tọ̀ọ́tọ́, tí inú àwọn olúkópa méjèjì pẹ̀lú BAnQ sí dùn sí èsì àdánwò náà. Gbogbo àwọn àwòrán tí a yyà ní a lè rí ní Wikimedia Commons.

Bytes in brief

Community roundup

Newsworthy

Worth reading (or watching)


Thanks for reading! To receive a monthly talk page update about new issues of Books & Bytes, please add your name to the subscriber's list. For email delivery of the newsletters, please subscribe here. To suggest items for the next issue, please contact the editor, The Interior (talk · contribs) at en:Wikipedia:The Wikipedia Library/Newsletter/Suggestions.